Fífẹ̀ ọ̀nà
How much data a network path can carry in a period of time.
Iye dátà tí ọ̀nà nẹ́tíwọ́ọ̀kì lè gbé nínú àkókò.
Approved Yoruba tech terms in Networking.
Browse
How much data a network path can carry in a period of time.
Iye dátà tí ọ̀nà nẹ́tíwọ́ọ̀kì lè gbé nínú àkókò.
Exchange of messages or media through digital networks and devices.
Pípàṣípààrọ̀ ọ̀rọ̀ tàbí média nípasẹ̀ nẹ́tíwọ́ọ̀kì àti ẹ̀rọ olóǹkà.
The system that maps domain names to IP addresses.
Ètò tó so orúkọ ibi-àyè mọ́ àdírẹ́sì IP.
A human-readable name that maps to network addresses.
Orúkọ tí ènìyàn lè ka tí ó so mọ́ àdírẹ́sì nẹ́tíwọ́ọ̀kì.
The global network that connects computers and services worldwide.
Nẹ́tíwọ́ọ̀kì àgbáyé tí ó so àwọn kọ̀ǹpútà pọ̀.
A numeric label that identifies a device on a network.
Àmì nọ́mbà tí ó fi ẹ̀rọ hàn lórí nẹ́tíwọ́ọ̀kì.
The delay before data starts transferring after a request.
Àkókò tí ó kọjá kí dátà tó bẹ̀rẹ̀ láti dé.
Agreed rules for how systems exchange data.
Àwọn òfin tí ètò fi ń pàṣípààrọ̀ dátà.
A device that forwards network traffic between networks.
Ẹ̀rọ tó ń darí dátà láàárín àwọn nẹ́tíwọ́ọ̀kì.
A private encrypted tunnel for network traffic across the public internet.
Ọ̀nà ìsopọ̀ àdáni tó pa dátà mọ́ kódà lórí íńtánẹ́ẹ̀tì.
Wireless networking that connects devices to a local network.
Ìsopọ̀ nẹ́tíwọ́ọ̀kì láì sí wáyà.