Ìrọ̀rùn ìlò
Designing products so people with diverse abilities can use them.
Ṣíṣe ètò kí onírúurú ènìyàn lè lò ó.
Tech nínú Yorùbá
Gbọ́ Yorùbá náà, mọ ìtumọ̀ rẹ̀, kí o sì rí bí a ṣe ń lò ó nínú ìgbésí ayé.
Àwọn ọ̀rọ̀ ìmọ̀-ẹ̀rọ ní Gẹ̀ẹ́sì àti Yorùbá — gbọ́ wọn, rí bí a ṣe ń lò wọn, kí o sì tẹ̀síwájú.
Designing products so people with diverse abilities can use them.
Ṣíṣe ètò kí onírúurú ènìyàn lè lò ó.
A step-by-step procedure for solving a problem or completing a task.
Àwọn ìgbésẹ̀ ṣíṣeto fún yíyanjú ìṣòro kan.
Software that finds and removes computer viruses and related malware.
Sọ́fitiwia tó ń wá, tó sì ń yọ kòkòrò-ẹ̀rọ àti ètò búburú mìíràn kúrò.
Application Programming Interface — a contract for software systems to talk to each other.
Ọ̀nà tí ètò kọ̀ǹpútà fi ń bá ara wọn sọ̀rọ̀.
Àwọn tó ń ṣe àtùmọ̀ — gba ọlá nígbà tí ọ̀rọ̀ àti àtúnṣe rẹ bá wọlé.
Fi ọ̀rọ̀ Gẹ̀ẹ́sì àti ìtúmọ̀ Yorùbá rẹ̀ sílẹ̀. A máa ṣàyẹ̀wò rẹ̀ kí ó tó di ti gbogbo ènìyàn.